1 Chronicles 1:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Eberi bí ọmọkunrin meji: Ekinni ń jẹ́ Pelegi, (nítorí pé ní àkókò tirẹ̀ ni àwọn eniyan ayé pín sí meji); ọmọ Eberi keji sì ń jẹ́ Jokitani,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati fun Eberi li a bi ọmọkunrin meji: orukọ ọkan ni Pelegi; nitori li ọjọ rẹ̀ li a pin aiye niya: orukọ arakunrin rẹ̀ si ni Joktani.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A bí àwọn ọmọ méjì fún Ébérì: Orúkọ ọ̀kan ni Pélégì, nítorí ní àkókò tirẹ̀ a pín ayé; orúkọ ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ ọkùnrin a sì máa jẹ́ Jókítanì.