1 Chronicles 1:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ofiri, Hafila ati Jobabu; Àwọn ni àwọn ọmọ Jokitani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Ofiri, ati Hafila, ati Jobabu. Gbogbo wọnyi li awọn ọmọ Joktani.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ófírì, Háfílà, àti Jóbábù. Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì jẹ́ àwọn ọmọ Jókítanì.