1 Chronicles 1:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àkọsílẹ̀ ìran wọn nìyí: Nebaiotu ni àkọ́bí Iṣimaeli, lẹ́yìn náà ni ó bí Kedari, Adibeeli, ati Mibisamu;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi ni iran wọn: akọbi Iṣmaeli, Nebaioti; ati Kedari, ati Adbeeli, ati Mibsamu,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nébáíótì àkọ́bí Íṣímáẹ́lì: Kédárì, Ádíbélì, Míbísámù,