1 Chronicles 1:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ marun-un tí Midiani bí ni Efa, Eferi ati Hanoku, Abida ati Elidaa. Gbogbo wọn jẹ́ arọmọdọmọ Ketura.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Midiani: Efa, ati Eferi, ati Henoki, ati Abida, ani Eldaa. Gbogbo wọnyi li awọn ọmọ Ketura.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọmọ Mídíánì: Éfà. Hénókì, Éférì, Ábídà àti Élídà. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Kétúrà.