1 Chronicles 1:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Elifasi ni Temani, Omari ati Sefi; Gatamu, Kenasi, Timna ati Amaleki.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Elifasi; Temani, ati Omari, Sefi, ati Gatamu, Kenasi, ati Timna, ati Amaleki.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Élífásì: Témánì, Ómárì, Ṣéfì, Gátamù àti Kénásì; làti Tímánà: Ámálékì.