1 Chronicles 10:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ogun gbóná janjan yí Saulu ká, àwọn tafàtafà rí i, wọ́n ta á lọ́fà, ó sì fara gbọgbẹ́,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ogun na si le fun Saulu, awọn tafàtafà si ba a, on si damu nitori awọn tafàtafà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìjà náà sì ń gbóná síi yí Sáúlù ká. Nígbà tí àwọn tafàtafà sì lé e bá, wọ́n sì sá a lọ́gbẹ́.