1 Chronicles 11:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn olókìkí mìíràn ninu àwọn ọmọ ogun Dafidi nìwọ̀nyí: Asaheli, arakunrin Joabu; ati Elihanani, ọmọ Dodo, ará Bẹtilẹhẹmu;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn akọni ọkunrin ọmọ ogun rẹ̀ ni Asaheli arakunrin Joabu, Elhanani, ọmọ Dodo, ara Betlehemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn akọni ọkùnrin náà nìyí: Ásáhélì arákùnrin Jóábù, Élíhánánì ọmọ Dódò láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,