1 Chronicles 11:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dafidi lọ ń gbé ibi ààbò náà, nítorí náà ni wọ́n ṣe ń pe ibẹ̀ ní ìlú Dafidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si ngbe inu ilu odi, nitorina ni nwọn fi npè e ni ilu Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì mú lọ sókè ibùgbé nínú odi alágbára, bẹ́ẹ̀ ní a sì ń pè é ni ìlú Dáfídì.