1 Chronicles 11:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dafidi bẹ̀rẹ̀ sí di alágbára sí i, nítorí pé OLUWA àwọn ọmọ ogun wà pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni Dafidi nga, o si npọ̀ si i: nitori ti Oluwa awọn ọmọ-ogun wà pẹlu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Dáfídì sì jẹ́ alágbára kún alágbára nítorí pé OLÚWA àwọn ọmọ ogun wà pẹ̀lú Rẹ̀.