1 Chronicles 12:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn kan láti inú ẹ̀yà Juda ati ti ẹ̀yà Bẹnjamini wá sọ́dọ̀ Dafidi níbi ààbò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Benjamini ati Juda si tọ Dafidi wá lori òke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyòókù ará Bẹ́ńjámínì àti àwọn díẹ̀ ọkùnrin láti Júdà lọ sí ọ̀dọ̀ Dáfídì ní ibi gíga.