1 Chronicles 12:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Láti inú ẹ̀yà Aṣeri, ọ̀kẹ́ meji (40,000) ni àwọn ọmọ ogun tí wọ́n ti dira ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu ti Aṣeri, iru awọn ti njade lọ si ogun, ti o mọ̀ ogun iwé, ọkẹ meje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọkùnrin Áṣérì, àwọn tí ó ti ní ìmọ̀ sójà múra fún ogun ọ̀kẹ́ méje (40,000).