1 Chronicles 12:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Joela, ati Sebadaya, àwọn ọmọ Jehoramu, ará Gedori.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Joela, ati Sebadiah, awọn ọmọ Jerohamu ti Gedori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti Jóélà, àti Ṣébádíà àwọn ọmọ Jéróhámù láti Gédárì.