1 Chronicles 14:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi ṣe ohun tí Ọlọrun pa láṣẹ fún un, wọ́n pa àwọn ọmọ ogun Filistini láti Gibeoni títí dé Gasa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si ṣe gẹgẹ bi Ọlọrun ti paṣẹ fun u: nwọn si kọlù ogun awọn ara Filistia lati Gibeoni titi de Gaseri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì ṣe ohun tí Ọlọ́run ti pa láṣẹ fún wọn, wọ́n sì kọ lu àwọn ọmọ ogun Fílístínì láti gbogbo ọ̀nà Gíbíónì lọ sí Géṣérì.