1 Chronicles 14:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òkìkí Dafidi kàn káàkiri, OLUWA sì jẹ́ kí ẹ̀rù rẹ̀ máa ba gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Okiki Dafidi si kan yi gbogbo ilẹ ka. Oluwa si mu ki ẹ̀ru rẹ̀ ki o ba gbogbo orilẹ-ède.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni òkìkí Dáfídì tàn ká gbogbo ilẹ̀ káàkiri, OLÚWA sì mú kí gbogbo orílẹ̀ èdè bẹ̀rù Rẹ̀.