1 Chronicles 14:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi ṣe akiyesi pé Ọlọrun ti fi ìdí ìjọba òun múlẹ̀ lórí Israẹli, ati pé Ọlọrun ti gbé ìjọba òun ga nítorí àwọn ọmọ Israẹli eniyan rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si woye pe, Oluwa ti fi idi on joko li ọba lori Israeli, nitori a gbé ijọba rẹ̀ ga nitori ti awọn enia rẹ̀, Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì mọ Ísírẹ̀lì àti pé OLÚWA ti fi òun ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì àti pé Ìjọba Rẹ̀ ga jùlọ nítorí ti àwon ènìyàn Rẹ̀.