1 Chronicles 14:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Filistia ti dé sí àfonífojì Refaimu, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí gbógun ti àwọn ìlú tí ó wà níbẹ̀, wọ́n sì ń kó wọn lẹ́rú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ara Filistia si wá, nwọn si tẹ ara wọn ni afonifoji Refaimu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nísinsìn yìí àwọn ará Fílístínì ti wá láti gbógun ti àfonífojì Réfáímù;