1 Chronicles 15:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
láti inú ìdílé Usieli, ọkunrin mejilelaadọfa (112), Aminadabu ni olórí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Ussieli; Aminadabu olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ mejilelãdọfa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Méjìléláàdọ́fà nínú àwọn ọmọ Húsíélì; Ámínádábù olórí àti àwọn ẹbí Rẹ̀.