1 Chronicles 15:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Iye àwọn ọmọ Lefi tí ó kó jọ láti inú ìdílé kọ̀ọ̀kan nìwọ̀nyí: láti inú ìdílé Kohati: ọgọfa (120) ọkunrin, Urieli ni olórí wọn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Kohati; Urieli olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ ọgọfa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọgọ́fà nínú àwọn ọmọ Kóhátì; Úríélì olórí àti àwọn ẹbí Rẹ̀.