1 Chronicles 15:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti inú ìdílé Merari: igba ó lé ogún (220) ọkunrin, Asaaya ni olórí wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Merari; Asaiah olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ igba o le ogun:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Igba ó lé ogún nínú àwọn ọmọ Mórárì; Ásaíà olórí àti àwọn ẹbí Rẹ̀.