1 Chronicles 15:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti inú ìdílé Geriṣomu, aadoje (130) ọkunrin, Joẹli ni olórí wọn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Gerṣomu; Joeli olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ ãdoje:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àádóje nínú àwọn ọmọ Gésóní; Jóẹ́lì olórí àti àwọn ẹbí Rẹ̀.