1 Chronicles 15:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
láti inú ìdílé Elisafani, igba (200) ọkunrin, Ṣemaaya ni olórí wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Elisafani; Ṣemaiah olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ igba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Igba nínú àwọn ọmọ Élísáfálì; Ṣémáíà olórí àti àwọn ẹbí Rẹ̀.
Recommended Reading