1 Chronicles 15:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
láti inú ìdílé Heburoni, ọgọrin ọkunrin, Elieli ni olórí wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Hebroni; Elieli olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ ọgọrin:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọgọ́rin nínú àwọn ọmọ Hébírónì; Élíélì olórí àti àwọn ẹbí Rẹ̀.
Recommended Reading