1 Chronicles 16:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ máa fi orúkọ rẹ̀ ṣògo, kí ọkàn àwọn tí wọn ń sin OLUWA kún fún ayọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ma ṣogo li orukọ rẹ̀ mimọ́; jẹ ki ọkàn awọn ti nwá Oluwa ki o yọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyìn nínú orúkọ Rẹ̀ mímọ́; jẹ kí ọkàn àwọn tí ó yin OLÚWA kí ó yọ̀.