1 Chronicles 16:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọn kò tíì pọ̀ pupọ, tí wọn kò sì jẹ́ nǹkan, tí wọ́n jẹ́ àjèjì níbẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ẹnyin wà ni kiun ni iye, ani diẹ kiun, ati atipo ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọn kéré ní iye, wọ́n kéré gidigidi, wọ́n sì jẹ́ àlejò níbẹ̀,