1 Chronicles 16:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
tí wọn ń lọ káàkiri láti orílẹ̀-èdè kan dé ekeji, láti ìjọba kan sí òmíràn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si nlọ lati orilẹ-ède de orilẹ-ède, ati lati ijọba kan de ọdọ enia miran;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
wọ́n rìn kiri láti orílẹ̀ èdè sí orílẹ̀-èdè láti ìjọba kan sí èkejì.