1 Chronicles 16:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
kò jẹ́ kí ẹnikẹ́ni ni wọ́n lára, ó bá àwọn ọba wí nítorí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On kò jẹ ki ẹnikẹni ki o ṣe wọn ni ìwọsi, nitõtọ, o ba awọn ọba wi nitori wọn,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò gba ọkùnrin kankan láyè láti pọ́n wọn lójú; nítorí ti wọn, ó bá àwọn ọba wí.