1 Chronicles 16:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ polongo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ sọ̀rọ ogo rẹ̀ ninu awọn keferi; ati iṣẹ-iyanu rẹ̀ ninu gbogbo enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kéde ìgbàlà à Rẹ̀ láàárin àwọn orílẹ̀-èdè, ohun ìyàlẹ́nu tí ó se láàrin gbogbo ènìyàn.