1 Chronicles 16:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé ère lásán ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù sọ di ọlọrun, ṣugbọn OLUWA ló dá ọ̀run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe gbogbo oriṣa awọn enia, ere ni nwọ́n: ṣugbọn Oluwa li o da awọn ọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí gbogbo àwọn Ọlọ́run orílẹ̀ èdè jẹ́ àwọn òrìsà, ṣùgbọ́n OLÚWA dá àwọn ọ̀run.