1 Chronicles 16:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ fi ògo tí ó yẹ orúkọ OLUWA fún un, ẹ mú ọrẹ wá sí iwájú rẹ̀! Ẹ sin OLUWA pẹlu ẹwà mímọ́,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ fi ogo fun Oluwa ti o yẹ fun orukọ rẹ̀: mu ọrẹ wá, ki ẹ si wá siwaju rẹ̀: ẹ sin Oluwa ninu ẹwà ìwa-mimọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
fún OLÚWA ní ìyìn nítorí orúkọ Rẹ̀. Gbé ọrẹ kí ẹ sì wá ṣíwájú Rẹ̀; Sìn OLÚWA nínú inú dídùn ìwà mímọ́ Rẹ̀.