1 Chronicles 16:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn igi igbó yóo kọrin ayọ̀ níwájú OLUWA, nítorí ó wá láti ṣe ìdájọ́ ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni awọn igi igbo yio ma ho niwaju Oluwa, nitori ti o mbọ wá ṣe idajọ aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni igi ti ọ̀dàn yóò kọrin, Wọn yóò kọrin fún ayọ̀ níwájú OLÚWA, Nítorí tí ó wá láti sèdájọ́ ayé.