1 Chronicles 16:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹni ìyìn ni OLUWA, Ọlọrun Israẹli, lae ati laelae!” Gbogbo àwọn eniyan sì dáhùn pe, “Amin”, wọ́n sì yin OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olubukún li Oluwa Ọlọrun Israeli lai ati lailai. Gbogbo awọn enia si wipe, Amin, nwọn si yìn Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olùbùkún ni OLÚWA, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, láé àti láéláé. Lẹ́yìn náà gbogbo àwọn ènìyàn wí pé “Àmín” wọ́n sì Yin OLÚWA.