1 Chronicles 17:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi bá lọ jókòó níwájú OLUWA, ó gbadura báyìí pé, “Kí ni èmi ati ilé mi jẹ́, tí o fi gbé mi dé ipò tí mo dé yìí?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi ọba si wá, o si joko niwaju Oluwa, o si wipe, Tali emi Oluwa Ọlọrun, ati kini ile mi, ti iwọ si mu mi de ihinyi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà, ọba Dáfídì wọlé lọ, ó sì jòkó níwájú OLÚWA ó sì wí pé: “Ta ni èmi, OLÚWA Ọlọ́run, àti ki ni ìdílé mi, tí ìwọ mú mi dé ibí?