1 Chronicles 18:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, Dafidi gbógun ti àwọn Filistini, ó ṣẹgun wọn, ó sì jagun gba ìlú Gati ati àwọn ìletò agbègbè rẹ̀ lọ́wọ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O SI ṣe lẹhin eyi, ni Dafidi kọlu awọn ara Filistia, o si ṣẹ́ wọn, o si gbà Gati ati ilu rẹ̀ lọwọ awọn ara Filistia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní àkókò kan, Dáfídì kọlu àwọn ará Fílístínì, ó sì sẹ́gun wọn. Ó sì mú Gátì àti àwọn ìlétò agbègbè Rẹ̀ kúrò lábẹ́ ìdarí àwọn ará Fílístínì.