1 Chronicles 18:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dafidi ṣẹgun àwọn ará Moabu, wọ́n di iranṣẹ rẹ̀, wọ́n sì ń san ìṣákọ́lẹ̀ fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si kọlu Moabu, awọn ara Moabu si di iranṣẹ Dafidi, nwọn si mu ọrẹ wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì borí àwọn ará Móábù, wọ́n sì di ọmọ-ẹ̀yìn Rẹ̀, wọ́n sì mú owó òde wá.