1 Chronicles 18:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn ará Siria wá láti Damasku, láti ran Hadadeseri, ọba Soba lọ́wọ́, Dafidi gbógun tì wọ́n, ó sì pa ẹgbaa mọkanla (22,000) ninu àwọn ọmọ ogun wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn ara Siria ti Damasku wá lati ran Hadareseri ọba Soba lọwọ, Dafidi pa ẹgbã mọkanla enia ninu awọn ara Siria.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbá ti àwọn ará Áráméà nì ti Dámásíkù wá láti ran Hadadésérì ọba Ṣóbà lọ́wọ́, Dáfídì lu ẹgbàá méjì wọn bọ lẹ̀.