1 Chronicles 19:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí ó yá, Nahaṣi, ọba àwọn ará Amoni kú, Hanuni ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O SI ṣe lẹhin eyi, ni Nahaṣi ọba awọn ọmọ Ammoni kú, ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní àkókò yí, Náháṣì ọba àwọn ará Ámónì kú, ọmọ Rẹ̀ sì rọ́pò Rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.