1 Chronicles 19:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó fi àwọn ọmọ ogun yòókù sí abẹ́ Abiṣai, arakunrin rẹ̀, wọ́n sì dojú kọ àwọn ọmọ ogun Amoni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi iyokù awọn enia le Abiṣai arakunrin rẹ̀ lọwọ, nwọn si tẹ ogun si awọn ọmọ Ammoni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fi ìyókù àwọn ọkùnrin náà sí abẹ́ àkóso Ábíṣáì arákùrin Rẹ̀, a sì tẹ́ wọn kí wọn dojúkọ àwọn ará Ámónì.