1 Chronicles 19:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ogun Amoni tò lẹ́sẹẹsẹ siwaju ẹnubodè ìlú wọn, ṣugbọn àwọn ọba tí wọ́n bẹ̀ lọ́wẹ̀ wà lọ́tọ̀ ninu pápá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Ammoni si jade wá, nwọn si tẹ ogun niwaju ẹnu-ibode ilu na: awọn ọba ti o wá si wà li ọtọ̀ ni igbẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ará Ámónì jáde wá, wọ́n sì dá isẹ́ ogun ní àbáwọlé sí ìlú ńlá wọn, nígbà tí àwọn ọba tí ó wá, fún rara wọn wà ni orílẹ̀ èdè tí ó sí sílẹ̀.