1 Chronicles 2:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ramu bí Aminadabu, Aminadabu bi Naṣoni, olórí pataki ninu ẹ̀yà Juda,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ramu si bi Amminadabu; Amminadabu si bi Naṣoni, ijoye awọn ọmọ Juda;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rámù sì ni baba Ámínádábù, àti Ámínádábù baba Náṣónì olórí àwọn ènìyàn Júdà.