1 Chronicles 2:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jese bí ọmọ meje; orúkọ wọn nìyí bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn: Eliabu ni àkọ́bí, lẹ́yìn náà Abinadabu ati Ṣimea;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jesse si bi Eliabu akọbi rẹ̀, ati Abinadabu àtẹle, ati Ṣimma ẹkẹta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jésè sì ni Baba Élíábù àkọ́bí Rẹ̀; ọmọ ẹlẹ́ẹ̀kẹjì sì ni Ábínádábù, ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni Ṣíméà,