1 Chronicles 2:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Onamu bí ọmọ meji: Ṣamai ati Jada. Ṣamai náà bí ọmọ meji: Nadabu ati Abiṣuri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Onamu si ni, Ṣammai, ati Jada. Awọn ọmọ Ṣammai ni; Nadabu ati Abiṣuri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ónámù: Ṣámáì àti Jádà. Àwọn ọmọ Ṣámáì: Nádábù àti Ábísúrì.