1 Chronicles 2:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nadabu, arakunrin Abiṣuri náà bí ọmọ meji: Seledi ati Apaimu; ṣugbọn Seledi kò bímọ títí tí ó fi kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Nadabu; Seledi, ati Appaimu: ṣugbọn Seledi kú laini ọmọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Nádábù Ṣélédì àti Ápáímù. Ṣélédì sì kú láìsí ọmọ.