1 Chronicles 2:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jada, arakunrin Ṣamai, bí ọmọ meji: Jeteri ati Jonatani, ṣugbọn Jeteri kò bímọ títí tí ó fi kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Jada arakunrin Ṣammai; Jeteri, ati Jonatani; Jeteri si kú laini ọmọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Jádà, arákùnrin Ṣámáì: Jétérì àti Jónátanì. Jétérì sì kú láìní ọmọ.