1 Chronicles 2:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tamari, iyawo ọmọ Juda, bí ọmọ meji fún un: Peresi ati Sera.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tamari aya-ọmọ rẹ̀ si bi Faresi ati Sera fun u. Gbogbo awọn ọmọ Juda jẹ marun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Támárì, aya ọmọbìnrin Júdà, ó sì bí Fárésì àti Ṣérà sì ní ọmọ márùn ún ní àpapọ̀