1 Chronicles 2:49 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Maaka yìí kan náà ni ó bí Ṣaafu, baba Madimana, tí ó tẹ ìlú Madimana dó, ati Ṣefa, baba Makibena ati Gibea, àwọn ni wọ́n tẹ ìlú Makibena ati ìlú Gibea dó. Kalebu tún bí ọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Akisa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si bi Ṣaafa baba Madmana, Ṣefa baba Makbena, ati baba Gibea: ọmọbinrin Kalebu si ni Aksa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì bí Ṣáfà baba Mákíbénà, Ṣéfà baba Mákíbénà àti baba Gíbéà: ọmọbìnrin Kélẹ́bù sì ni Ákíṣà.