1 Chronicles 2:52 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣobali baba Kiriati Jearimu ni baba gbogbo àwọn ará Haroe, ati ìdajì àwọn tí ń gbé Menuhotu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Ṣobali baba Kirjat-jearimu ni ọmọ; Haroe, ati idaji awọn ara Manaheti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ṣóbálì baba Kíríátì-Jéárímù ni: Háróè, ìdajì àwọn ará Mánáhítì.