1 Chronicles 2:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Sera bí ọmọ marun-un: Simiri, Etani, Hemani, Kalikoli ati Dada.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Sera; Simri, ati Etani, ati Hemani, ati Kalkoli, ati Dara: gbogbo wọn jẹ marun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ṣérà: Ṣímírì, Étanì, Hémánì, Kálíkólì àti Darà, gbogbo wọn jẹ́ márùn ún.