1 Chronicles 2:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Hesironi ni Jerameeli, Ramu ati Kelubai.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Hesroni pẹlu ti a bi fun u; Jerahmeeli, ati Ramu, ati Kelubai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ tí a bí fún Hésírónì ni: Jéráhímélì, Rámù àti Kélẹ́bù.