1 Chronicles 20:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí ó ń fi àwọn ọmọ Israẹli ṣe ẹlẹ́yà, Jonatani, ọmọ Ṣimea, arakunrin Dafidi bá pa á.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati o pe Israeli ni ija, Jonatani ọmọ Ṣimea arakunrin Dafidi pa a.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó fí Íṣírẹ́lì sẹ̀sín Jónátanì ọmọ Ṣíméà, àrákùnrin Dáfídì, sì pa á.