1 Chronicles 20:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìran òmìrán, ará Gati ni àwọn mẹtẹẹta; Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ ni ó sì pa wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn wọnyi li a bi fun òmiran ni Gati; nwọn si tipa ọwọ Dafidi ṣubu, ati ipa ọwọ awọn iranṣẹ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ̀nyí ni ìran ọmọ Ráfà ní Gátì, wọ́n sì subú sí ọwọ́ Dáfídì àti àwọn ọkùnrin Rẹ̀.